Matiu 25:42 BM

42 Nítorí nígbà tí ebi ń pa mí, ẹ kò fún mi ní oúnjẹ jẹ. Òùngbẹ ń gbẹ mí, ẹ kò fún mi ní omi mu.

Ka pipe ipin Matiu 25

Wo Matiu 25:42 ni o tọ