Matiu 26:19 BM

19 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn náà ṣe bí Jesu ti pàṣẹ fún wọn. Wọ́n sì tọ́jú gbogbo nǹkan fún àsè Ìrékọjá.

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:19 ni o tọ