Matiu 26:34 BM

34 Jesu wí fún un pé, “Mo fẹ́ kí o mọ̀ dájúdájú pé ní alẹ́ yìí, kí àkùkọ tó kọ, ìwọ yóo sẹ́ mi ní ẹẹmẹta.”

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:34 ni o tọ