Matiu 27:11 BM

11 Jesu bá dúró siwaju gomina. Gomina bi í pé, “Ìwọ ni ọba àwọn Juu bí?”Jesu ní, “O ti fi ẹnu ara rẹ sọ ọ́.”

Ka pipe ipin Matiu 27

Wo Matiu 27:11 ni o tọ