Matiu 28:20 BM

20 Ẹ máa kọ́ wọn láti kíyèsí gbogbo nǹkan tí mo pa láṣẹ fun yín. Kí ẹ mọ̀ dájú pé mo wà pẹlu yín ní ìgbà gbogbo, títí dé òpin ayé.”

Ka pipe ipin Matiu 28

Wo Matiu 28:20 ni o tọ