Matiu 3:9 BM

9 Ẹ má ṣe rò lọ́kàn yín pé, ‘A ní Abrahamu ní baba.’ Nítorí mo ń sọ fun yín pé Ọlọrun lè gbé ọmọ dìde fún Abrahamu láti inú òkúta wọnyi.

Ka pipe ipin Matiu 3

Wo Matiu 3:9 ni o tọ