Matiu 6:15 BM

15 Ṣugbọn bí ẹ kò bá dáríjì àwọn eniyan, Baba yín kò ní dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.

Ka pipe ipin Matiu 6

Wo Matiu 6:15 ni o tọ