Matiu 6:34 BM

34 Nítorí náà, ẹ má ṣe àníyàn nípa nǹkan ti ọ̀la; nítorí ọ̀la ni nǹkan ti ọ̀la wà fún; wahala ti òní nìkan ti tó fún òní láì fi ti ọ̀la kún un.

Ka pipe ipin Matiu 6

Wo Matiu 6:34 ni o tọ