Matiu 8:1 BM

1 Nígbà tí Jesu sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè, ọ̀pọ̀ àwọn eniyan ń tẹ̀lé e.

Ka pipe ipin Matiu 8

Wo Matiu 8:1 ni o tọ