Romu 10:16 BM

16 Ṣugbọn kì í ṣe gbogbo wọn ni ó gba ìyìn rere yìí gbọ́. Aisaya ṣá sọ ọ́ pé, “Oluwa, ta ni ó gba ohun tí a sọ gbọ́?”

Ka pipe ipin Romu 10

Wo Romu 10:16 ni o tọ