Romu 11:5 BM

5 Bẹ́ẹ̀ náà ló rí ní àkókò yìí, àwọn kan kù tí Ọlọrun yàn nítorí oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Romu 11

Wo Romu 11:5 ni o tọ