Romu 11:8 BM

8 gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ pé,“Ọlọrun fún wọn ní iyè tí ó ra,ojú tí kò ríran,ati etí tí kò gbọ́ràn títí di òní olónìí.”

Ka pipe ipin Romu 11

Wo Romu 11:8 ni o tọ