Romu 12:4 BM

4 Nítorí bí a ti ní ẹ̀yà ara pupọ ninu ara kan, tí gbogbo àwọn ẹ̀yà ara wọnyi kì í sìí ṣe iṣẹ́ kan náà,

Ka pipe ipin Romu 12

Wo Romu 12:4 ni o tọ