Romu 13:11 BM

11 Ó yẹ kí ẹ mọ irú àkókò tí a wà yìí, kí ẹ tají lójú oorun. Nítorí àkókò ìgbàlà wa súnmọ́ tòsí ju ìgbà tí a kọ́kọ́ gbàgbọ́ lọ.

Ka pipe ipin Romu 13

Wo Romu 13:11 ni o tọ