Romu 13:6 BM

6 Ìdí kan náà nìyí tí ẹ fi ń san owó-orí. Iṣẹ́ Ọlọrun ni àwọn aláṣẹ ń ṣe, nǹkankan náà tí wọ́n tẹra mọ́ nìyí.

Ka pipe ipin Romu 13

Wo Romu 13:6 ni o tọ