Romu 14:17 BM

17 Nítorí ìjọba Ọlọrun kì í ṣe ọ̀ràn nǹkan jíjẹ ati nǹkan mímu, ọ̀ràn òdodo, alaafia ati ayọ̀ ninu Ẹ̀mí Mímọ́ ni.

Ka pipe ipin Romu 14

Wo Romu 14:17 ni o tọ