Romu 14:19 BM

19 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á máa lépa àwọn nǹkan tí ń mú alaafia wá, ati àwọn nǹkan tí yóo yọrí sí ìdàgbàsókè láàrin ara wa.

Ka pipe ipin Romu 14

Wo Romu 14:19 ni o tọ