Romu 15:28 BM

28 Nítorí náà, nígbà tí mo bá parí ètò yìí, tí mo ti fi ọwọ́ ara mi fún wọn ní ohun tí a rí kójọ, n óo gba ọ̀dọ̀ yín kọjá sí Spania.

Ka pipe ipin Romu 15

Wo Romu 15:28 ni o tọ