Romu 2:16 BM

16 ní ọjọ́ tí Ọlọrun yóo rán Jesu láti ṣe ìdájọ́ ohun ìkọ̀kọ̀ gbogbo tí ó wà ninu eniyan gẹ́gẹ́ bí ìyìn rere tí mò ń waasu.

Ka pipe ipin Romu 2

Wo Romu 2:16 ni o tọ