Romu 2:22 BM

22 Ìwọ tí o sọ pé kí eniyan má ṣe àgbèrè, ṣé ìwọ náà kì í ṣe àgbèrè? Ìwọ tí o kórìíra oriṣa, ṣé o kì í ja ilé ìbọ̀rìṣà lólè?

Ka pipe ipin Romu 2

Wo Romu 2:22 ni o tọ