Romu 2:25 BM

25 Ilà tí o kọ ní anfaani, bí o bá ń pa Òfin mọ́. Ṣugbọn tí o bá rú Òfin, bí àìkọlà ni ìkọlà rẹ rí.

Ka pipe ipin Romu 2

Wo Romu 2:25 ni o tọ