Romu 6:5 BM

5 Bí a bá sọ wá di ọ̀kan náà pẹlu Jesu ninu ikú, a óo sọ wá di ọ̀kan náà pẹlu rẹ̀ ninu ajinde.

Ka pipe ipin Romu 6

Wo Romu 6:5 ni o tọ