Romu 8:36 BM

36 Ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Nítorí rẹ a wà ninu ewu ikú lojoojumọ,wọ́n sì ṣe wá bí aguntan tí wọ́n fẹ́ lọ pa.”

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:36 ni o tọ