Romu 8:6 BM

6 Lílépa àwọn nǹkan ti ẹran-ara nìkan a máa yọrí sí ikú, ṣugbọn lílépa àwọn nǹkan ti Ẹ̀mí a máa fúnni ní ìyè ati alaafia.

Ka pipe ipin Romu 8

Wo Romu 8:6 ni o tọ