Hos 11:3 YCE

3 Mo kọ́ Efraimu pẹlu lati rìn, mo dì wọn mu li apa, ṣugbọn nwọn kò mọ̀ pe mo ti mu wọn lara dá.

Ka pipe ipin Hos 11

Wo Hos 11:3 ni o tọ