Hos 14:1 YCE

1 ISRAELI, yipadà si Oluwa Ọlọrun rẹ, nitori iwọ ti ṣubu ninu aiṣedẽde rẹ.

Ka pipe ipin Hos 14

Wo Hos 14:1 ni o tọ