Hos 14:8 YCE

8 Efraimu yio wipe, Kili emi ni fi òriṣa ṣe mọ? Emi ti gbọ́, mo si ti kiyesi i: emi dabi igi firi tutù. Lati ọdọ mi li a ti ri èso rẹ.

Ka pipe ipin Hos 14

Wo Hos 14:8 ni o tọ