Hos 4:16 YCE

16 Nitori Israeli ṣe agidi bi ọmọ malu alagidi; nisisiyi Oluwa yio bọ́ wọn bi ọdọ-agùtan ni ibi ayè nla.

Ka pipe ipin Hos 4

Wo Hos 4:16 ni o tọ