Hos 6:1 YCE

1 Ẹ wá, ẹ jẹ ki a yipadà si Oluwa: nitori o ti fà wa ya, on o si mu wa lara da; o ti lù wa, yio si tun wa dì.

Ka pipe ipin Hos 6

Wo Hos 6:1 ni o tọ