Hos 7:10 YCE

10 Igberaga Israeli si njẹri si i li oju rẹ̀; nwọn kò si yipadà si Oluwa Ọlọrun wọn, bẹ̃ni fun gbogbo eyi nwọn kò si wá a.

Ka pipe ipin Hos 7

Wo Hos 7:10 ni o tọ