2. A. Ọba 10:3 YCE

3 Ki ẹ wò ẹniti o sàn jùlọ ati ti o si yẹ jùlọ ninu awọn ọmọ oluwa nyin, ki ẹ gbé e ka ori-itẹ́ baba rẹ̀, ki ẹ si jà fun ile oluwa nyin.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 10

Wo 2. A. Ọba 10:3 ni o tọ