2. A. Ọba 10:7 YCE

7 O si ṣe, nigbati iwe na de ọdọ wọn, ni nwọn mu awọn ọmọ ọba, nwọn si pa ãdọrin ọkunrin, nwọn si kó ori wọn sinu agbọ̀n, nwọn si fi wọn ranṣẹ si i ni Jesreeli.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 10

Wo 2. A. Ọba 10:7 ni o tọ