2. A. Ọba 12:9 YCE

9 Ṣugbọn Jehoiada alufa mu apoti kan, o si dá ideri rẹ̀ lu, o si fi i si ẹba pẹpẹ na, li apa ọtún bi ẹnikan ti nwọ̀ inu ile Oluwa lọ: awọn alufa ti o si ntọju iloro na fi gbogbo owo ti a mu wá inu ile Oluwa sinu rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 12

Wo 2. A. Ọba 12:9 ni o tọ