2. A. Ọba 13:18 YCE

18 O si wipe, Kó awọn ọfà na. O si kó wọn. O si wi fun ọba Israeli pe, Ta si ilẹ. On si ta lẹrinmẹta, o si mu ọwọ duro.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 13

Wo 2. A. Ọba 13:18 ni o tọ