2. A. Ọba 14:11 YCE

11 Ṣugbọn Amasiah kò fẹ igbọ́. Nitorina Jehoaṣi ọba Israeli gòke lọ; on ati Amasiah ọba Juda si wò ara wọn li oju ni Betṣemeṣi, ti iṣe ti Juda.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 14

Wo 2. A. Ọba 14:11 ni o tọ