2. A. Ọba 14:21 YCE

21 Gbogbo awọn enia Juda si mu Asariah ẹni ọdun mẹrindilogun, nwọn si fi i jọba ni ipò Amasiah baba rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 14

Wo 2. A. Ọba 14:21 ni o tọ