2. A. Ọba 15:18 YCE

18 O si ṣe eyi ti o buru li oju Oluwa: on kò si lọ kuro ninu ẹ̀ṣẹ Jeroboamu ọmọ Nebati ẹniti o mu Israeli ṣẹ̀, li ọjọ rẹ̀ gbogbo.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 15

Wo 2. A. Ọba 15:18 ni o tọ