2. A. Ọba 15:25 YCE

25 Ṣugbọn Peka ọmọ Remaliah, olori-ogun rẹ̀, dì rikiṣi si i, o si kọlù u ni Samaria, li odi ile ọba, pẹlu Argobu, ati Arie, ati ãdọta enia ninu awọn ọmọ Gileadi pẹlu rẹ̀: o si pa a, o si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 15

Wo 2. A. Ọba 15:25 ni o tọ