2. A. Ọba 15:38 YCE

38 Jotamu si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi baba rẹ̀, Ahasi ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 15

Wo 2. A. Ọba 15:38 ni o tọ