2. A. Ọba 15:7 YCE

7 Asariah si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀; nwọn si sìn i pẹlu awọn baba rẹ̀, ni ilu Dafidi: Jotamu ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 15

Wo 2. A. Ọba 15:7 ni o tọ