6 Li akokò na, Resini ọba Siria gbà Elati pada fun Siria, o si lé awọn enia Juda kuro ni Elati: awọn ara Siria si wá si Elati, nwọn si ngbe ibẹ titi di oni yi.
Ka pipe ipin 2. A. Ọba 16
Wo 2. A. Ọba 16:6 ni o tọ