2. A. Ọba 17:11 YCE

11 Nibẹ ni nwọn si sun turari ni gbogbo ibi giga wọnni, bi awọn keferi ti Oluwa kó lọ niwaju wọn ti ṣe; nwọn si ṣe ohun buburu lati rú ibinu Oluwa soke.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 17

Wo 2. A. Ọba 17:11 ni o tọ