2. A. Ọba 17:7 YCE

7 O si ṣe, nitoriti awọn ọmọ Israeli dẹṣẹ si Oluwa Ọlọrun wọn, ti o ti mu wọn gòke lati ilẹ Egipti wá, kuro labẹ ọwọ Farao ọba Egipti, ti nwọn si mbẹ̀ru ọlọrun miran.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 17

Wo 2. A. Ọba 17:7 ni o tọ