2. A. Ọba 17:9 YCE

9 Awọn ọmọ Israeli si ṣe ohun ikọ̀kọ ti kò tọ́ si Oluwa Ọlọrun wọn, nwọn si kọ́ ibi giga fun ara wọn ni gbogbo ilu wọn, lati ile-iṣọ awọn olùṣọ titi de ilu olodi.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 17

Wo 2. A. Ọba 17:9 ni o tọ