2. A. Ọba 18:16 YCE

16 Li akòko na ni Hesekiah ké gbogbo wura kuro lara awọn ilẹ̀kun ile Oluwa, ati kuro lara ọwọ̀n wọnni ti Hesekiah ọba Juda ti fi wura bò, o si fi wọn fun ọba Assiria.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 18

Wo 2. A. Ọba 18:16 ni o tọ