2. A. Ọba 19:22 YCE

22 Tani iwọ sọ̀rọ buburu si ti iwọ si kẹgàn? ati tani iwọ gbé ohùn rẹ si òke si, ti iwọ gbé oju rẹ ga si òke? ani si Ẹni-Mimọ Israeli.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 19

Wo 2. A. Ọba 19:22 ni o tọ