2. A. Ọba 19:3 YCE

3 Nwọn si wi fun u pe, Bayi ni Hesekiah wi, Ọjọ oni ọjọ wàhala ni, ati ti ibawi, ati ẹgàn: nitoriti awọn ọmọ de oju-ibí, kò si si agbara lati bi.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 19

Wo 2. A. Ọba 19:3 ni o tọ