2. A. Ọba 2:15 YCE

15 Awọn ọmọ awọn woli ti o wà ni Jeriko nihà keji si ri i, nwọn si wipe, Ẹmi Elijah bà le Eliṣa. Nwọn si wá ipade rẹ̀; nwọn si tẹ̀ ara wọn ba silẹ niwaju rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 2

Wo 2. A. Ọba 2:15 ni o tọ