2. A. Ọba 2:6 YCE

6 Elijah si wi fun u pe, Emi bẹ̀ ọ, joko nihinyi; nitoriti Oluwa rán mi si Jordani. On si wipe, Bi Oluwa ti mbẹ, ati bi ẹmi rẹ ti mbẹ, emi kì o fi ọ silẹ. Awọn mejeji si jùmọ nlọ.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 2

Wo 2. A. Ọba 2:6 ni o tọ