2. A. Ọba 20:15 YCE

15 On si wipe, Kini nwọn ri ni ile rẹ? Hesekiah si dahùn wipe, Gbogbo nkan ti mbẹ ni ile mi ni nwọn ti ri: kò si nkan ninu iṣura mi ti emi kò fi hàn wọn.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 20

Wo 2. A. Ọba 20:15 ni o tọ